Iba o
Iba o,
OLODUMARE oba ajiki,
EDUMARE oba a ji ge,
Ogege Oba tiin gbele aye gun,
Ogbagba nla Oba tolode-Orun.
Iba o,
Ati yo ojo,
Ati wo oorun,
Iba kutukutu awo owuro,
Ganrin ganrin Awo osan gaangan,
Winrinwinrin Awo oru,
Ati okuku-su-wii, Awo oganjo.
Iba elewu ide,
iba elewu ala,
Iba irawo sasa n be lehin f’supa.
Afefelegelege Awo isalu aye,
Efuufulegelege Awo isalu orun,
Iba Ajagunmole oluwo ode Orun,
Iba Aromoganyin onibode aye oun orun,
Iba Awonamaja babalawo tii n komo nIFA oju orun.
Iba Esu lalu-okiri-oko, Kiri-ogo,
Iba Eyin Iyami,
Afinju eye tii n je loju oloko,
Afinju eye tii n fiye sapa tii n fiko sehin,
Afinju eye tii n fiye sapa tii n f’eekun sehin’
Afinju eye tii n fiye sapa tii n fehin sehin,
Afinju eye tii n fegungun sapa tii n fegungun sehin,
Afinju eye tii n firin n sapa tii n firin sehin,
Afinju eye tii n ina sapa tii n fina sehin.
Iba ILE,otete, langbua,
Aterere kari aye,
Agbohun maa fo, abiyamo tooto.
Iba IFA ohun OLODUMARE,
Iba Orunmila, eleri ipin,
Atori eni tio sunwon se,
Iba aboru, Aboye, Abosise.
Iba Ogun,yankan bi ogbe,
Iba Otarigidi-tii n se yeye Ogun,
Iba omobowu oun ewiri-maje,
Iba Ija, Iba, Osoosi,
Iba Olutasin tokoko bo Ogun,
Iba Ope ti a n tidi n be tii n tori gbe ni,
Iba Ope to fidi sekan to fori se pupo.
Iba Egbe oga-Ogo
Iba Ogba,
Iba Olunkori-Orisa ewe.
Iba Sango, Oluorojo,bambi-arigba ota segun,
Iba Haawa, Iba Gambe-olu,
Iba sere legelege tii n se gbaju fun Sango,
Iba Oya Oriri,obinrin gbongbonran tii n yoko re loko ebu.
Iba oke ganga, oke ganga,
Iba Aganju, Iba Mojelewu, Iba Okeere,
Iba Yemoja, Iba odo Ogun,
Iba Osaara, IbaToorosi,
Iba Iyalode lode oro,
Iba Moremi lode Ofa.
Iba Oba.
Iba o, Obatala, Oba taasa,
Oba patapata lode Iranje,
Iba Iranje’le Iba Iranje oko,
Iba Ifon-Osun,
Iba Igbin, Iba Igbin-Oosa,
Iba Alagemo-teerekange,
Je a gbo Je a to;
Iba Abamoda omo Oosa-Agbowujin,
Mo daba ire aje, ire aya/oko, ire omo, ire gbogbo,
Aba ti Alagemo bada lOosa-Oke n gba.
Iba Gunyan gunyan ile Ido,
Iba rokaroka obinrin Ibadan,
Iba Aje tii n somo Olu-Ibini,
Iba Okun tii n somo Ode-Irada,
Iba Oro, Oropoto pomupomu,
Tobi ‘mo lewelewe ti kan kan o sofun,
Iba Osanyin –mogboraye,
To gba opa lowo olokunrun sanu.
Iba Olokun Iba Olosa,
Iba Odu loogbo-oje,
Iba Osun awura-Olu,
Olooya-Iyun, Awede koto wemo,
Iba Iyami-Osoroniga lode-Ipokia,
Iba Ori-eni,
Iba Ikin-eni,
Iba Baba,
Iba Yeye,
Iba Oluwo,
Iba Ojugbona,
Iba Iparipa adaso-mamuro
Iba eyin Isoro-Orun
Iba ara Ile.
Awa juba kee je kiba wa se, ASE!

The Yoruba Spiritual Institute, Inc. is a 501(c)(3) non-profit corporation registered in the State of Florida, with recognition as an official religious organization under the auspices of the United States Treasury. All donations are tax deductible. Please consult your tax preparer for more information.
El Instituto Yoruba Espiritual, es una organización 501 (c) (3) sin fines de lucroregistrada en el Estado de la Florida, con el reconocimiento como una organización religiosa oficial bajo los auspicios del Tesoro de los Estados Unidos. Todas las donaciones son deducibles de impuestos. Por favor, consulte a su preparador de impuestos para más información.